Ijúbà

Eriwoya! Eriwoya! Eriwoya!

Ìbà Akoda, ìbà Àseda;

ìbà bàbá, ìbà yèyè, ìbà àti waàiyéojo,

ìbà àti wóó Òrun, ìbà Ìyá mi apoki lèsè Òsun ado maa pòn eèwu

A jí pòn ola ntó ki Oba olóomi.

Ìbà Òrunmìlá Eléri ìpin, Ajé kóógun o tó je

ìbà Odù Ògúngún ni so,

ìbà Èsù Làálu

ìbà irínwo imònlé

ìbà olóorí fún mèrerin Àiyé

Éjé kó èse fún wa!

Ìbà aTraducción

Plegaria.


¡Albricias, albricias, albricias!

Mis respetos al primero, mi pleitesía al último

(Iniciados en el ashe de Orunmilá)

Respeto a los padres, a las madres, que por su poder de lluvia fertilizadora

revitalizan la tierra.

Respeto a los seres que habitan los cielos, entre quienes mi madre,

En la gloria a los pies de Oshun

Protegida entre algodones en la calabaza de su Venerado.

No hay comentarios: